asa bimpé [live] şarkı sözleri
Bimpe n bami wi
O f'owo s'inu business mi
Emi'rẹ ko l'egbe
O kan s'aju mi bimọ ni
O gbọ pe o n mọmi l'oju
O l'anu gboha nipa business mi
Ọrọ emi'rẹ ko l'eni
Ẹgbọn rẹ n fẹ mi ni
Ẹgbọn rẹ to n fẹ mi lọwọ ni o
Mo dare fun o
Ẹgbọn rẹ
Ẹgbọn rẹ oh
Ẹ ba mi sọ fun baby yẹn
Fun baby yẹn
To wọle yẹn
Ẹ ba n kilọ fun
Ẹ kilọ fun yo
Ẹ ba mi sọ fun sisi yẹn
Fun sisi yẹn
To kun atike
Ẹ ba n kilọ fun
Ẹ kilọ fun, yo, yo, yo
Bimpe n ri mi fin
O wuwa ọmọ aisi imoye
Mo ronu piwa da
Ọmọ inu mi lon bami wi
Ile ana mo n rẹ lo yo
Wọn kuku jẹ n sinmi
Irẹ o l'apọnle
O dẹ fẹ k'eyan fẹ ẹ sile
Ẹgbọn rẹ to n fẹ mi lọwọ ni o
Mo dare fun o
Ẹgbọn rẹ
Ẹgbọn rẹ, oh
Ẹ ba mi sọ fun baby yẹn
Fun baby yẹn
To w'ole yẹn
Ẹ ba n kilọ fun
Ẹ kilọ fun yo
Ẹ ba mi sọ fun sisi yẹn
Fun sisi yẹn
To kun atike
Ẹ ba n kilọ fun
Ẹ kilọ fun, yo, yo, yo
Ẹgbọn rẹ to n fẹ mi lọwọ ni o
Mo dare fun o
Ẹgbọn rẹ
Ẹgbọn rẹ, oh
Ẹ ba mi sọ fun baby yẹn
Fun baby yẹn
To wọle yẹn
Ẹ ba n kilọ fun
Ẹ kilọ fun yo
Ẹ ba mi sọ fun baby yẹn
To gbọmọ pọn
To k'atike
Ẹ ba n kilọ fun
Ẹ sọrọ fun yo
Ẹ ba mi sọ fun baby yẹn
Fo soke, ko rin nilẹ, ti o ba wọ, ko lari mọlẹ
Ẹ ba mi kilọ fun
Ẹ kilọ fun yo
Ẹ ba mi sọ fun baby yẹn
Ko fo soke, ko rin nilẹ, ko rin l'Ọfa
Ẹ ba n kilọ fun
Ẹ sọrọ fun yo, yo, yo