asa bimpé [live] şarkı sözleri

Bimpe n bami wi O f'owo s'inu business mi Emi'rẹ ko l'egbe O kan s'aju mi bimọ ni O gbọ pe o n mọmi l'oju O l'anu gboha nipa business mi Ọrọ emi'rẹ ko l'eni Ẹgbọn rẹ n fẹ mi ni Ẹgbọn rẹ to n fẹ mi lọwọ ni o Mo dare fun o Ẹgbọn rẹ Ẹgbọn rẹ oh Ẹ ba mi sọ fun baby yẹn Fun baby yẹn To wọle yẹn Ẹ ba n kilọ fun Ẹ kilọ fun yo Ẹ ba mi sọ fun sisi yẹn Fun sisi yẹn To kun atike Ẹ ba n kilọ fun Ẹ kilọ fun, yo, yo, yo Bimpe n ri mi fin O wuwa ọmọ aisi imoye Mo ronu piwa da Ọmọ inu mi lon bami wi Ile ana mo n rẹ lo yo Wọn kuku jẹ n sinmi Irẹ o l'apọnle O dẹ fẹ k'eyan fẹ ẹ sile Ẹgbọn rẹ to n fẹ mi lọwọ ni o Mo dare fun o Ẹgbọn rẹ Ẹgbọn rẹ, oh Ẹ ba mi sọ fun baby yẹn Fun baby yẹn To w'ole yẹn Ẹ ba n kilọ fun Ẹ kilọ fun yo Ẹ ba mi sọ fun sisi yẹn Fun sisi yẹn To kun atike Ẹ ba n kilọ fun Ẹ kilọ fun, yo, yo, yo Ẹgbọn rẹ to n fẹ mi lọwọ ni o Mo dare fun o Ẹgbọn rẹ Ẹgbọn rẹ, oh Ẹ ba mi sọ fun baby yẹn Fun baby yẹn To wọle yẹn Ẹ ba n kilọ fun Ẹ kilọ fun yo Ẹ ba mi sọ fun baby yẹn To gbọmọ pọn To k'atike Ẹ ba n kilọ fun Ẹ sọrọ fun yo Ẹ ba mi sọ fun baby yẹn Fo soke, ko rin nilẹ, ti o ba wọ, ko lari mọlẹ Ẹ ba mi kilọ fun Ẹ kilọ fun yo Ẹ ba mi sọ fun baby yẹn Ko fo soke, ko rin nilẹ, ko rin l'Ọfa Ẹ ba n kilọ fun Ẹ sọrọ fun yo, yo, yo
Sanatçı: Asa
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 4:15
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
Asa hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı