bbbabel magun şarkı sözleri

BBbabel O lóhùn rídin lọ má shè O lóhùn èṣin O lóhùn 69 lọ má shè O mọ mathematics O lóhùn o mọ pé Pẹ̀ emi o ni wọlé Ṣò má dùn Má dùn má dùn Magun Iyawo mi ní ilẹ̀ Oníjẹkújẹ Kò sí nkan nkan sẹ́ ti kò lè jẹ̀ Kò lè wíne Kò lè limpopo Kò ṣè exercise Ó tóbi bí hippopo Mi wá lẹ̀ score away goal pẹ̀lú secretary Tó ní nice body chemistry In fact, á n ti sex chat Ó text back Pẹ̀, I love you Say na me fresh pass Ó wo office pẹ̀lú miniskirt Ó turn around I see say she really set Ó wà jọkò sọ̀ri table mi Ó sì button láti disable mí Shey kí n ṣẹ̀ Abi kí n má shè Those are the thoughts in my head Ṣò má dùn Má dùn má dùn Magun O lóhùn rídin lọ má shè O lóhùn èṣin O lóhùn 69 lọ má shè O mọ mathematics O lóhùn o mọ pé Pẹ̀ emi o ni wọlé Ṣò má dùn Má dùn má dùn Magun O lóhùn rídin lọ má shè O lóhùn èṣin O lóhùn 69 lọ má shè O mọ mathematics O lóhùn o mọ pé Pẹ̀ emi o ni wọlé Ṣò má dùn Má dùn má dùn Magun Tá bá ní kà ṣọkọ̀ sọ́jà À bá ra lẹ è Magun àbọ̀ ọ̀rìṣà ni Magun òrò nlá ni Ò màn tí ṣubú Ò n ṣubú
Sanatçı: BBbabel
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 2:22
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
BBbabel hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı