ccc sanctum choir iyin in the crowd şarkı sözleri

Olorun ti mo gb'ojule Sa ra re ma re Oba ti mo fi yin fun o Oba to nse le ri mu se o Okun pin ya Agbara re ma ni O so omi kikoro di adun Agbara re ma ni Agan d'olomo Agbara re ma ni Odi Jericho wo lu le Agbara re ma ni O ku ise Oluwa o seun Dansaki re Olorun Oba re re Osuba re rè o Arugbo Ojo o Iyin ogo ye o Baba Iyin ogo ye o Baba
Sanatçı: CCC Sanctum Choir
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 1:53
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
CCC Sanctum Choir hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı