ccc sanctum choir ju wura (album version) şarkı sözleri

Ohun ta ni O ju wura lo o Ehn Ogo ta ni o ju wura lo o Ehn Ohun ta ni O ju wura lo o Ehn Ogo ta ni o ju wura lo o Ehn A ti ra wa pada A ti d'omo Omo ileri A ti jogun iye Ainipekun Ogo ni ti wa A ti ra wa pada A ti d'omo Omo ileri A ti jogun iye Ainipekun Ogo ni ti wa Ohun ta ni O ju wura lo o Ehn Ogo ta ni o ju wura lo o Ehn Ohun ta ni O ju wura lo o Ehn Ogo ta ni o ju wura lo o Ehn A ti ra wa pada A ti d'omo Omo ileri A ti jogun iye Ainipekun Ogo ni ti wa A ti ra wa pada A ti d'omo Omo ileri A ti jogun iye Ainipekun Ogo ni ti wa Ko su wa lati ma ko orin Ti igbani Ogo f'olorun halleluyah A le fi igbabo k'orin na S'oke kikan Ogo f'Olorun halleluyah Omo Olorun ni eto Lati ma bu s'ayo Pe ona yi nye wa si Okan wa ns'aferi Re Nigb'o se a o de afin Oba wa ologo Ogo f'olorun Halleluyah Owo o le ra Aiye o le gba lowo wa Ohun ta ni ju wura lo Ohun ta ni ju wura lo Ohun ta ni ju wura lo Owo o le ra Aiye o le gba lowo wa Owo o le ra Aiye o le gba lowo wa Ohun ta ni ju wura lo Ohun ta ni ju wura lo Ohun ta ni ju wura lo Owo o le ra Aiye o le gba lowo wa Baba mimo lo fi fun wa Nipa eje Jesu Ore ofe wa s'aiye Luli O ju wura, fadaka Ohun ta o le na loja ni o Iyebiye ogo nla ni E di mu o Ijo mimo Owo o le ra Aiye o le gba lowo wa Ohun ta ni ju wura lo Ohun ta ni ju wura lo Ohun ta ni ju wura lo Owo o le ra Aiye o le gba lowo wa Airopo ibukun L'eledumare fi fun wa o Repete repete o repete Ibukun aitan o repete Ibukun aiyeraiye L'eledumare fi fun wa o Repete repete o repete Ibukun aitan o repete Ibukun orun o L'ore ofe to ga ju lo Repete repete o repete Ibukun aitan o repete Ohun ta fi fun wa O ju wura lo o Repete repete o repete Ibukun aitan o repete Mo nran yin le ti Luli yi ju wura lo o Repete repete o repete Ibukun aitan o repete Ohun t'agbe l'Oshoffa lowo O ju wura lo o Repete repete o repete Ibukun aitan o repete Ohun t'agbe le Bada lowo O ju wura lo o Repete repete o repete Ibukun aitan o repete Ohun t'agbe le Sanctum lowo O ju wura lo o Repete repete o repete Ibukun aitan o repete Ogo ijo mimo O ju wura lo o Repete, repete o repete Ibukun aitan o repete Ohun ta fi fun wa O ju wura lo o Repete repete o repete Ibukun aitan o repete Ohun ta fi fun wa O ju wura lo o Repete repete o repete Ibukun aitan o repete
Sanatçı: CCC Sanctum Choir
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 7:14
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
CCC Sanctum Choir hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı