ccc sanctum choir sutana şarkı sözleri

Aso ogo nla ni Mi o ti ju wo rara Aso ogo mimo ni Mi o fi sere Aiye n buwa pe aso yi O ma ni yi Won tun wipe A nse bi egbe awon ogboni Ko ye won Ko le ye won Bo se wun o Lo n s'ola re O pe mi s'agbo Ki n j'alabapin Ninu ore ofe Mimo yi O Bo akisa ese Kuro Lara mi O ra mi pada O wo mi la so titun Aiye e gbo Aso mimo ni mo wo Funfun nene Aso mimo ni mo wo Funfun nene Aso mimo ni mo wo Funfun nene Sutana yi Mimo ni o Aso mimo ni mo wo Funfun nene Aso mimo ni mo wo Funfun nene Aso mimo ni mo wo Funfun nene Ogo yi Didan ni o Funfun nene Aso mimo ni mo wo Funfun nene Aso mimo ni mo wo Funfun nene Aso mimo ni mo wo Funfun nene Sutana yi Mimo ni o Aso mimo ni mo wo Funfun nene Aso mimo ni mo wo Funfun nene Aso mimo ni mo wo Funfun nene Ogo yi Didan ni o
Sanatçı: CCC Sanctum Choir
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 2:58
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
CCC Sanctum Choir hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı