cenation ikorodu oga şarkı sözleri

Ikorodu Ikorodu Ikorodu Oga Scriilevel Ati gbe de to gun to gun Ati gbe de ti ja ti ja Ati gbe de ti jo ti jo Ati gbe de to rin to rin Ikorodu lawa ta leyin Ikorodu lo ga Ta lo ga Ti yin Ikorodu lawa ta leyin Ikorodu lo ga o Ta lo ga Ti yin Brt leyin Yellow bus lawa ta lo ga Ti yin ikorodu oga la wa se mo Ko la ni abi se mo jo lawal ta ba Sa re gan olohun e ma le lawa we Getting the money We winning The game and we getting the Fame too awa la da igboro ru Won tu gbon ni ketu awa la tu Drop Orin tan tu feel ni phase 2 Mo de fe de jos kan ma gbo ni Plateau mehn i'm so hungry for The success I ain't gonna take a Nap till i put my damn hood on The map Ati gbe de to gun to gun Ati gbe de ti ja ti ja Ati gbe de ti jo ti jo Ati gbe de to rin to rin Ikorodu lawa ta leyin Ikorodu lo ga Ta lo ga Ti yin Ikorodu lawa ta leyin Ikorodu lo ga o Ta lo ga Ti yin Vip leyin regular la wa Alejo Leyin oni le la wa casino leyin Bet9ja la wa awa hustle gan Shortcut leyin wa ikorodu sa ni Ile wa na here hustle start omo No be eazi movement Bi ti zagadat Oba ikorodu Ikorodu oga awon Ijoye ikorodu oga senator bayo Ikorodu Oga honourable sob Ikorodu oga Ati gbe de to gun to gun Ati gbe de ti ja ti ja Ati gbe de ti jo ti jo Ati gbe de to rin to rin Ikorodu lawa ta leyin Ikorodu lo ga Ta lo ga Ti yin Ikorodu lawa ta leyin Ikorodu lo ga o Ta lo ga Ti yin Ceo lakers ab fresh akinola tv Qdot alagbe toheebzola zlatan Ibile oti ye e scrii level
Sanatçı: Cenation
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 3:01
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
Cenation hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı