chaerin kim rendezvous: yoruba şarkı sözleri

Mo n rán e lo bayi. Mo mu e si okan mi O le gan… o du n mi gan Su gban mo n rán e lọ Iwo ni kan ni mo fẹràn. Mo duro de e Su gban mo n je ko lọ A pa de lana. O wa ni a la mi, o pade mi pelu ife ati omije lo ju re ni ro nu Se o ni ife mi? Se O si fe je ki n lọ? Se O duro de mi Ni gbagbogbo ni mo few a ni tosi Jowo ma fi mi le. Mi o daju pe o rán ti mi O mu gbogbo ife mi. O dara ti o ba rán ti mi Bayi, mo lala idunu. Rán ibamuje mi kuro. Mu ayo mi wa O fẹràn mi nitori o ri inu mi. Su gban mo fẹràn re si Mo dabobo re. mi o ni je ko lọ Iyebiye mi, ife mi. Jowo wi pe a wa lailai Ki o gbe ke le mi mu ọwọ mi dani dada Ma tu ọwọ wa mo
Sanatçı: Chaerin Kim
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 4:55
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
Chaerin Kim hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı