daddy.b ayomi [studio record] şarkı sözleri

Ayomitide Ayomitide Ayomitide Oluwa lo da bo bo mi Ayomitide Ayomitikun Ayomitikun Oluwa lo da bo bo mi Ayomitikun Ni igba isoro Nigba itura Oluwa lo da bo bo mi Ayomitide Ota o le ri mi gbe se Ayomitide Oluwa lo da bo bo mi Ebi ara eba mi yo Ayomitide Oluwa lo da bo bo mi Odo tagba eba mi se ope Oluwa lo da bo bo mi Ayomitide Ope ni fun JESU Ope ni fun Baba Ope ni fun Emi mimo Eba mi Jo Eba mi yo Eba mi yo Oluwa lo da bo bo mi Ayomitide Eba mi so pe Eba mi Jo Oluwa lo da bo bo mi Ayomitide
Sanatçı: Daddy.B
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 3:12
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
Daddy.B hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı