Daeze

Halleluyah (orin iyin) (feat. Belladonna)

daeze halleluyah (orin iyin) (feat. belladonna) şarkı sözleri

Ewa gbo Ire t'oluwa ti se Laye mi O funmi layo O semi lore Mo ri anu gba I've come to testify Thank you Lord For the blessings And your mercy Endures forever E se o baba lo ke Mo yin o oh Glory to your name Ewa ba mi yin Jesu logbo Hallelujah orin isegun Ewa ba mi yin Jesu logo Hallelujah orin iyin Ewa ba mi yin Jesu logbo Hallelujah orin isegun Ewa ba mi yin Jesu logo Hallelujah orin iyin Melo ni mba ka I cannot count it all Iwo ni ma sin titi aye mi Mo ni alafia Mo wa laye ati laaye Anu ni mo ri gba This is my testimony Thank you Lord For the blessings And your mercy Endures forever E se o baba lo ke Mo yin o oh Glory to your name Ewa ba mi yin Jesu logbo Hallelujah orin isegun Ewa ba mi yin Jesu logo Hallelujah orin iyin Ewa ba mi yin Jesu logbo Hallelujah orin isegun Ewa ba mi yin Jesu logo Hallelujah orin iyin Orin orin igbala Orin orin isegun Orin orin igbala Orin orin isegun Orin orin igbala Orin orin isegun Orin orin igbala Orin orin isegun Hallelujah oh Hallelujah Hallelujah Hallelujah Ah orin isegun Ah orin iyin Ah orin isegun Ah orin iyin
Sanatçı: Daeze
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 3:09
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
Daeze hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı