dainywest bamise şarkı sözleri

Me wanna go faraway bàbá jọwọ bámi ṣe, Májẹ̀ kẹ mi ṣẹgbẹ I just wan making money Olúwa jọ̀ gbọ̀ tẹ́mi oo I will never fall down Me i just wan, wanna going higher I wanna making money everytime Olúwa jọ̀ wọ̀ jọ̀ gbádùrà, I pray Small boy want to ball out Olúwa jọ̀ wọ̀ jọ̀ gbádùrà Olúwa jọ̀ gbọ̀ tẹ́mi oo I just wan make this Moni yi oh oh oh Irẹ̀ ayọ ni mọfẹ̀, má ṣe je kọ̀tà kọ́ ba tẹ́mi je Because me i really making money Olúwa jọ̀ gbọ̀ tẹ́mi oo, gbọ̀ tẹ́mi oh oh oh Everyday me I wake, me I stand on my knees I’ll pray, I’ll cry on to God I’ll say Tọ́ri wipe, otà ṣare, Ṣare, wọ́n ti gbẹ̀ mu, gbẹ̀ mu Run after lati ṣe mi, ṣe mi But I cry unto God, Olúwa jọ̀ má jẹ̀ kí Na me be God sent to my family I wanna be the remedy, I wanna keep dem in company Olúwa jọ̀ wá gbádùrà mi Olúwa jọ̀ wá bámi ṣe, je kẹmi omo re kọ́rẹ̀ délé ọọ Gbádùrà mi ọ, wá gbọ̀ tẹ́mi ọ, Olúwa wá ṣe tẹ́mi ọọ Small boy want to ball out Olúwa jọ̀ wọ̀ jọ̀ gbádùrà Olúwa jọ̀ gbọ̀ tẹ́mi oo I just wan make this Moni yi oh oh oh Irẹ̀ ayọ ni mọfẹ̀, má ṣe je kọ̀tà kọ́ ba tẹ́mi je Because i wan really making money Olúwa jọ̀ gbọ̀ tẹ́mi oo, gbọ̀ tẹ́mi oh oh oh Have been hustle to get this paper Reason every, everytime Bàbá jọ̀wọ̀ ọ, wá gbádùrà ọ Yeh ye Ṣebi wọ́n ni ikọ̀kọ̀ dúdù ni èkọ̀ fúfùn, Ti jàde ọ, má ti jàde ọ, Ṣe mi ni ọmọ ari idunu, Bàbá jọ̀ má ṣe mi ni ari pọ̀sẹ" Yeh ye Wọ́ ni kílóde kíló fẹ̀ ṣe I am praying for more blessing Ki ọ̀tá kọ̀n kọ̀n má ṣe mi lẹ̀ṣẹ, Olúwa jọ̀wọ̀ kọ̀ wá gbádùrà mi Have been crying on to God everytime Olúwa jọ̀ wá gbádùrà, Wá gbọ̀ tẹmi ọ̀ Wá ṣe tẹmi ọ̀, Olúwa gbádùrà mi ọ̀ Small boy want to ball out Olúwa jọ̀ wọ̀ jọ̀ gbádùrà Olúwa jọ̀ gbọ̀ tẹ́mi oo I just wan make this Moni yi oh oh oh Irẹ̀ ayọ ni mọfẹ̀, má ṣe je kọ̀tà kọ́ ba tẹ́mi je Because i wan really making money Olúwa jọ̀ gbọ̀ tẹ́mi oo, gbọ̀ tẹ́mi oh oh oh
Sanatçı: Dainywest
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 2:57
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
Dainywest hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı