d.dat agba ola şarkı sözleri
Still don't have enough but never beg to feed
Okun arà mí le, no sickness have waid me down
In all Circumstances you're my God,you're my God
Bi mì ranti àgbelèbú o,I feel blessed I got a grace
I brainstorm what it is I can call you,you that dwelleth in zion
Mo ri pé Oba olá ni o jé Olórun òrò
Ìwo làgbàlagbà Olá, Elérù ni yì
Ubangiji mi, mo dúpe è sé
Àgbàlagbà Olá, Ató faratì
Naraekelegi, Olórun òrò
I've got a God the king of grace, the only one I see, whose hands are never too short Láti gbàmí
I've got a God the king of wealth, the only one I see, who owns the whole world nd all in It
I brainstorm what it is I can call you,you that dwelleth in zion
Mo ri pé Oba olá ni o jé , Olórun òrò
Ìwo làgbàlagbà Olá, Elérù ni yì
Ubangiji mi, mo dúpe è sé
Àgbàlagbà Olá, Ató faratì
Naraekelegi, Olórun òrò

