elizavocat ire şarkı sözleri
Emi ni Ire
Ire ni mi
Eni ba ni mi roju rere
Ire owo, ire omo o o,a'talafia n ba mi gbe
Ire ni mi o
Odidandan kori mi sore
Ire ni moje o oo
Odidandan kin rin kore
Bi nba woju mi ma rire oo
Bi n ba weyin mi ma rire
Nitooto Ire ati anu
Ni yo mato mi leyin lojo aye mi gbogbo