femi arrival igbehin mi adara şarkı sözleri

Igbehin mi adara, igbehin mi adara Tori pe mo fehin ti jesu olugbala igbehin mi adara Igbehin mi adara Adara Igbehin mi adara Tori pe mo fehin ti jesu olugbala igbehin mi adara Igbehin mi adara, igbehin mi adara Tori pe mo fehin ti jesu olugbala igbehin mi adara Igbehin mi adara Loruko jesu Igbehin mi adara Tori pe mo fehin ti jesu olugbala igbehin mi adara Igbehin eda nika wo Eledami o, ranmi lowo ki serere Igbehin eda nika wo Eledami o, ranmi lowo ki serere Omode subu ounwo ohun iwaju Ohun to gbo mode subu o eyin lowa Maje ki mosi layee Maje ki babiala Maje ki mosi laye e Maje ki babiala Igbehin mi adara, igbehin mi adara Tori pe mo fehin ti jesu olugbala igbehin mi adara Igbehin mi adara Adara Igbehin mi adara Tori pe mo fehin ti jesu olugbala igbehin mi adara Igbehin mi adara, igbehin mi adara Tori pe mo fehin ti jesu olugbala igbehin mi adara Igbehin mi adara Loruko jesu Igbehin mi adara Tori pe mo fehin ti jesu olugbala igbehin mi adara Ote tabile ounje sile niwaju mi Oda ororo sori mi ajo mi waku repete Awa togbekele oluwa A o dabi oke sioni Oke yi duro gban gban a ko le si nidi o Igbehin mi adara, igbehin mi adara Tori pe mo fehin ti jesu olugbala igbehin mi adara Igbehin mi adara Adara Igbehin mi adara Tori pe mo fehin ti jesu olugbala igbehin mi adara Igbehin mi adara, igbehin mi adara Tori pe mo fehin ti jesu olugbala igbehin mi adara Igbehin mi adara Loruko jesu Igbehin mi adara Tori pe mo fehin ti jesu olugbala igbehin mi adara Eni toba moyi wura owu lalefi wura lelo wo Eni toba mo jesu loluwa Ohun lole ni igbehin rere Eni toba moyi wura owu lalefi wura lelo wo Eni toba mo jesu loluwa Ohun lole ni igbehin rere Igbehin mi adara, igbehin mi adara Tori pe mo fehin ti jesu olugbala igbehin mi adara Igbehin mi adara Adara Igbehin mi adara Tori pe mo fehin ti jesu olugbala igbehin mi adara Igbehin mi adara, igbehin mi adara Tori pe mo fehin ti jesu olugbala igbehin mi adara Igbehin mi adara Loruko jesu Igbehin mi adara Tori pe mo fehin ti jesu olugbala igbehin mi adara
Sanatçı: Femi Arrival
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 4:39
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
Femi Arrival hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı