Gabriel Olukolu

Celestial Palm Sunday Hymns Medly (feat. Cxrissysax)

gabriel olukolu celestial palm sunday hymns medly (feat. cxrissysax) şarkı sözleri

Ẹyọ, Ẹyọ, ẹ ho, ẹ yọ s'Olùgbàlà Eyo, eyo, e ho, e yo s'Olugbala Olùgbàlà n g'ẹṣin bọ s'ode aiye Ọmọ ẹhin nké Hossanah s'ọba wa Kristi lo mbọ, ẹ wolẹ fún Ẹ wolẹ fún Kristi lo mbọ, ẹ wolẹ fún Jésù lógún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ T'àwọn áńgẹ́lì nkọ Hossanah Jésù lógún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ T'àwọn áńgẹ́lì ńkọ́ Hossanah Ẹ wá ká lọ jọ́sìn, Jésù ló jọba Ẹ wá bá wa jọ́sìn, Jésù ló jọba Jésù lógún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ T'àwọn áńgẹ́lì nkọ Hossanah Jésù lógún kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ T'àwọn áńgẹ́lì ńkọ́ Hossanah Ẹ wá ká lọ jọ́sìn, Jésù ló jọba Ẹ wá bá wa jọ́sìn, Jésù ló jọba Ará, ẹ bá mi ká lọ Pàdé Olúwa mi o Ará, ẹ bá mi ká lọ Pàdé Olúwa mi o Ni Jerusalem Ni Ìlú ayọ̀ Ni Jerusalem Ni Ìlú ayo Àwọn Áńgẹ́lì njo Àwọn Maleka nyọ Àwọn Áńgẹ́lì njo Àwọn Maleka nyọ Nwọn nke Hossanah S'Ọmọ Dáfídì Nwọn nke Hossanah S'Ọmọ Dáfídì
Sanatçı: Gabriel Olukolu
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 4:42
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
Gabriel Olukolu hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı