gaise baba ojonlo şarkı sözleri

Ojonlo Ojonlo Ojonlo Ojonlo Ojonlo Ojonlo Ojonlo Ojonlo Akoko ko ma duro 'wo to'n f'igbala d'oni 'wo to'n f'igbala d'ola 'wo to'n f'igbala fa'le Ojonlo Jowo ma jafara Tete se ki'o ro'nu igbeyin aiye B'oni ti ri, ola ko ri be Bi o ba se se se, to ko Jesu sile Bi o ba b'aiye lo, to lo gbe lukudi To ba wa d'igbeyin aiye, to be wa so emi re nu Asenu re yio ti po to Ko s'ebo fun asenu, ko s'ebo fun asenu, alaigboran Ko s'ebo fun asenu, ko s'ebo fun asenu, iwo alaigboran
Sanatçı: Gaise Baba
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 1:27
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
Gaise Baba hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı