gbenga afolayan where is my testimony? şarkı sözleri

Ẹri mi da (where is my testimony) Mo ti duro lojukan tipẹ (I've waited on the same spot for a long time) E ha ti jẹ oluwa mi (Why my Lord) Ẹri mi ma ma da o (Where is my testimony) Yio ti pẹ́tó to fi dá mi lóhùn (How long'd you answer me) Egungun mi n di gbígbẹ lọ e (My bone is drying) Tori ẹkun mi lojojumọ (cos of my daily cry) Ẹri mi da oluwa (Where's my testimony Lord) Ẹri mi da (where is my testimony) Mo ti duro lojukan tipẹ (I've waited on the same spot for a long time) E ha ti jẹ oluwa mi (Why my Lord) Ẹri mi ma ma da o (Where is my testimony) Ẹri mi da (where is my testimony) Mo ti duro lojukan tipẹ (I've waited on the same spot for a long time) E ha ti jẹ oluwa mi (Why my Lord) Ẹri mi ma ma da o (Where is my testimony) Sebi wọn ni ẹni toba ba ẹ sowo pọ (They've said anyone who trade with you) Ko ni jokun ofo-o laye (Would not lose) Kilo wa se temi tọrọ mi o ja sayọ o (Why is my case not turning into joy) Ẹmi mi n sunmọ isa oku Olúwa mi (My soul is approaching dealth, Lord) Jẹ́ ọ̀rọ̀ mi o ja sayọ o (Let my situation turn into joy) Ẹri mi da (where is my testimony) Mo ti duro lojukan tipẹ (I've waited on the same spot for a long time) E ha ti jẹ oluwa mi (Why my Lord) Ẹri mi ma ma da o (Where is my testimony) Ẹri mi da (where is my testimony) Mo ti duro lojukan tipẹ (I've waited on the same spot for a long time) E ha ti jẹ oluwa mi (Why my Lord) Ẹri mi ma ma da o (Where is my testimony) Mo mọ-ọn se, mi o mọ-ọn se ni (Even if I know it or not) Mo mọrọsọ, mi o mọrọsọ ni (Even if I know how to talk or not) Mo qualify, mi o qualify o (Even if I qualify or not) Jẹ́ kaanu mi ko se ọ (Have mercy on me) Pasẹ fun osu tawayi (Command this month) Ko san gbese ohun rere to jẹ mi (To pay me back with good tthings it owes me) Kilẹ oni tosu oluwa (Before the evening today) Jẹ́ ki n lẹri ayọ o (Let me have joyous testimony) Ẹri mi da (where is my testimony) Mo ti duro lojukan tipẹ (I've waited on the same spot for a long time) E ha ti jẹ oluwa mi (Why my Lord) Ẹri mi ma ma da o (Where is my testimony) Ẹri mi da (where is my testimony) Mo ti duro lojukan tipẹ (I've waited on the same spot for a long time) E ha ti jẹ oluwa mi (Why my Lord) Ẹri mi ma ma da o (Where is my testimony) Ẹri mi da (where is my testimony) Mo ti duro lojukan tipẹ (I've waited on the same spot for a long time) E ha ti jẹ oluwa mi (Why my Lord) Ẹri mi ma ma da o (Where is my testimony) Ẹri mi da (where is my testimony) Mo ti duro lojukan tipẹ (I've waited on the same spot for a long time) E ha ti jẹ oluwa mi (Why my Lord) Ẹri mi ma ma da o (Where is my testimony)
Sanatçı: Gbenga Afolayan
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 2:22
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
Gbenga Afolayan hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı