gbenga beulah alaanu mi şarkı sözleri

Kosohun to n jẹ ju ọpẹ lọ Kosohun to jẹ ju ọpẹ lọ Ọpẹ lounjẹ rẹ ìyìn l'ohunje rẹ Kosohun to njẹ jo'pẹ lọ Mo ronú jinlẹ̀ titi pe bi mo ba file pọti ti mọ fona ro'ka kín se Oúnjẹ rẹ ni Ọlọrun mi Oó gb'owo lọwọ mi fún èémí ti Mo n mi Bẹẹ o gbeje lowo mi fún àbò rẹ Lori mi lori ẹbi nigba gbogbo Ni Mósè wipe o ṣe Baaba Alaanu mi Tal'a ba fio we ninu aye Awọn alagbara pọ jan tirẹrẹ ṣugbọn iru rẹ ni o sí ọlọrun mi Sebi iwọ lo dana sori papa Papa njo ṣugbọn igbẹ o run Aditu Nla ma sa lorọ rẹ Apoti to seku Usa lo tun sọ Obedi-edomu dọlọla, Káábíèsí o ma si o Ọba Téní Kan o le bawi jọ ooo Iwọ lororun aiku Iwọ lororun aiṣa Iwọ lororun aiti Iwọ lororun airi Akikitan, ayinyintan apeepetan Atabatubu Oba teni kan o ridi rẹ Oogo rẹ ti mọlẹ to, ogo rẹ ti Mọlẹ to o Olutanju mi Alaanu Oluranlowo mi iwọ l'ọpẹ yẹ fún Olutanju Alaanu mi Oluranlowo mi iwọ l'ọpẹ tosi o Bẹ'da bamonu ro yíò ma fimoore ọlọrun Mosún laṣalẹ o Jimi saye l'owurọ yi, agbara mi Kọ aanu ni mo rigba awoni Magbeje o ṣe olutanju ayé mi Ose o Olutanju mi Alaanu mi Oluranlowo mi iwo l'ope yefun O olutanju mi alaanu mi Oluranlowo Iwọ l'ọpẹ tosí o Èmi o san tọrọ kọbọ fún èmí rè Ti mi mo n mi ọpọ lo n be Lọwọ ti nwọn sanwó èémí wọn Ọlọrun bẹ Aye wo, Baba bami Muwon larada ki won o le yin Ọ Ki won o le se bi moti ṣe Olutanju mi Alaanu mi Oluranlowo mi iwo l'ope ye Fún O olutanju mi Alaanu mi Oluranlowo mi iwọ l'ope tosí o Lori ile mi lori ebi ni gbogbo Ana mi óo jen loju ẹkun ọlọrun MiO lereke Ose, ogun ìdílé Dide lati dènà ogo rẹ l'ayé mi Iwọ lo gbe mi leke o gbe mi Bori awọn ọta mi Olutanju mi Alaanu mi Oluranlowo mi iwọ l'ọpẹ yẹ Fún o Olutanju mi Alaanu mi Oluranlowo mi iwọ l'ọpẹ yẹ Fún olutanju mi Alaanu mi Oluranlowo mi iwọ l'ọpẹ tọ si o Modupe ore re lori Aye mi Alaanu mi mo m'ope wa Modupe ore re lori Aye mi Alaanu mi o mo gbe ọ ga Modupe ore re lori Aye mi Alaanu mi mo m'ope wa Modupe ore re lori Aye mi Alaanu mi o mo gbe ọ ga Ibiti o durosi fúnmi Tobi Oluwa boba jẹniyen won a ti Ma siregun Apata igbala mi oseun o Alaanu Mi mo gbe o ga ga ga o Modupe ore re lori Aye mi Alaanu mi mo m'ope wa Modupe ore re lori Aye mi Alaanu mi o mo gbe ọ ga Inu mi dun oluwa, inu dùn Ọlọrun Inu mi dun oluwa,inu mi dun Ọlọrun mi Akaika niye o l'ore to se funmi T'inu mi fi dun oluwa Inu mi dun oluwa, inu dùn Ọlọrun mi Inu mi dun oluwa,inu mi dun Ọlọrun mi Akaika niye o l'ore to se funmi T'inu mi fi dun oluwa Se ore jijẹ o laa fẹ sọ ni tabi ore Mimu oluwa oseun, iṣẹ rẹ toobi O lori Aye mi, ko ma lafiwe o Se Bàbá Mo n gun Moto Lojojumo B'ẹni mo ngun okada Kaa kiri, ẹ pade Nile'wosan óò Jẹ ko jẹ t'emi, e padi ni motuary Ko jẹ ko jẹ tiwa ati beebeelo, L'ore tio Sefun mi, t'inu mi fi n dun Olúwa Inu mi dun oluwa, inu dùn Ọlọrun Inu mi dun oluwa,inu mi dun Ọlọrun mi Akaika niye o l'ore to se funmi T'inu mi fi dun oluwa Ọlọrun ona ọpẹ mi pọ Olorun ọna ọpẹ mi pọ Ọnà ọpẹ mi pọ lọdọ rẹ baba Agba Olorun ọna ọpẹ mi pọ Ọlọrun ona ọpẹ mi pọ Olorun ọna ọpẹ mi pọ Ọnà ọpẹ mi pọ lọdọ rẹ kolounka Olorun ọna ọpẹ mi pọ Ọlọrun ona ọpẹ mi pọ Olorun ọna ọpẹ mi pọ Ọnà ọpẹ mi pọ lọdọ rẹ kolounka Olorun ọna ọpẹ mi pọ Gbope mi Jesu Gbope gbope gbope gbope Gbope mi o Baba Agbanilagbatan Gbope mio Baba Gbope mio Baba Atobajaye Gbope o Baba Ọlọrun Beulah Ọlọrun Bàbá agba Gbope mi o baba
Sanatçı: Gbenga Beulah
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 19:13
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
Gbenga Beulah hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı