gbenga beulah moni jesu l'oluwa şarkı sözleri

Moni Jesu L'oluwa o moti ni Moni Jesu L'oluwa o mo lohùn Gbogbo Moní Jesu L'oluwa o moti ni Moní Jesu L'oluwa o mo lohùn Gbogbo Nígbà mo mọ nire wa mi ri Nigba mo mọ nire wọlé mi Lọjọ mo mọ lẹ kun ni Dayo Jesu Moni Jesu L'oluwa o moti ni Moni Jesu L'oluwa o mo lohùn Gbogbo Boba ni Jesu Laye rẹ o wa L'ohun gbogbo oo Bo bá ní Jésù laye rẹ iya iya rẹ A dopin Bo bá ní Jésù laye rẹ wa l'ohun gbogbo óò Bó bá ní Jésù laye rẹ iya rẹ a dopin Biwọ bá le gbagbọ wa da'segun Biwọ bá le gbagbọ wa ni'ye Ayérayé Bó bá ní Jésù laye rẹ o wa L'ohun gbogbo oo Bó bá ní Jésù láyé re Iya rẹ a dopin Moni Jesu L'oluwa o moti ni Moni Jesu L'oluwa o mo lohùn Gbogbo Moní Jesu L'oluwa o moti ni Moni Jesu L'oluwa o mo lohùn Gbogbo Igba mo mọ nire wa mi ri Igba mo mọ nire wọlé mi Lọjọ mo mọ lẹ kun mi Dayo Jesu Moni Jesu L'oluwa o moti ni Moni Jesu L'oluwa o mo lohùn Gbogbo Akirisore ni Jésù yíò Akirisore Gbogbo bi to ba ti dé loti n sore Akirisore ni Jésù yíò Akirisore Gbogbo'bi to ba ti dé o loti n sore Ni kenani o so'mi doti, Ṣe ohun Lo laju afọju to'jioku Lasaru Dìde ko'to wa f'ẹmi rẹ lelẹ fun'ẹṣẹ wa Akirisore ni Jésù yíò Akirisore Gbogbo'bi to bati de o loti n sore Jesu o Jesu lọna Jesu lọna Òtítọ àti iye Too daju Kristi lọnà kristi lọnà otito ati Iye toodaja Akirisore asorekiri, Igba mo ti mọ laye mi ti dara Akirisore Ìgbà moti mọ na rẹ l'ayé mi ti Leto asorekiri Akirisore asorekiri, Igba mo ti mọ laye mi ti dara Akirisore Ìgbà moti mọ na rẹ l'ayé mi ti Leto asorekiri Oya e wa gbaa o Olugbala Jésù Ọmọ Ọlọrun Olugbala To wa sile ayé Olugbala A gun lọkọ legbe nitori emi tire Won fun loti kikan mu nítorí emi'tirẹ A fun loti kikan mu ni Olugbala Ọrẹ ẹlẹsẹ Olugbala Nitori awa ẹlẹsẹ, agun lọkọ lẹgbẹ Olugbala Kawa ma bà segbé ka bàa lè yẹ Olugbala Yé wa gbaa o, Jesu nikan ni ona Olugbala Soti se tan lá ti gba Olugbala Oti ṣetan lati gba o
Sanatçı: Gbenga Beulah
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 5:58
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
Gbenga Beulah hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı