hadassah star iba baba agba şarkı sözleri

Iba Iba baba Agba Iba Iba Arugbo Ojo Osuba ologo didam Titi aye la o ma yin o Ekun oko oke Ekun oko farao Alagbada ina asaju ogun keyin ogun Iba Iba baba Agba Iba Iba Arugbo Ojo Osuba Ologo didan Titi aye la o ma yin o Ogbamu gbamu oju orun Osee ngbamu Okan soso ajanakun tin mi Gbo kiji kiji Akikitan, abubutan Aso isotan olodumare Adun darin adun forolo Arinu rode, olumero okan Alade ogo Ologo didan ologo pipe Eleruniyin, akoda aye Aseda orun Oba to le sohun gbogbo ninu Ohun gbogbo Osa gan dolomo mefa Opin okun pupa niya Aterere kari aye Aterere kari orun Ologun oluwa Jagun jagun mafitibon se Asaju ogun, akehin ogun Ajagun ma fi ti bon se Agbalagba oye Titi aye la o ma yin Iba iba baba agbalagba Abi abi arrugbo lailai Asuba ologo didan Titi aye lao ma yin o
Sanatçı: Hadassah Star
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 4:59
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
Hadassah Star hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı