harrysol time (feat. rap sultan) şarkı sözleri

Make it romantic Lókè lókè Eeeeccchhh Ekáalé ológì dé oo Lókè lókè Èmi tí mo da tí o da Oooouuuuhhh (Rap Sultan) Gbé mi sókè HarrySol To be like a gold You gotta be ready to enter fire (fire) I looked in the mirroooorrrhh(mirror) And I see no one around oo (around you) As my papa used to say (Papa used to say) Ómó mi má loma gbàgbé (má loma gbàgbé) And like my papa used to say (Papa used to say) Ómó mi time no dey wait Lókè lókè! sókè sókè! Gbé mi sókè! gbé mi sókè! Gbé mi dìde ee ah Lókè lókè! I keep on crying Gbé mi sókè (gbé mi sókè) I've been on the road I'm just all alone So many woes (so many woes) So many foes (so many) And as e dey go (as e dey go) We gats be living low (be living low) Cos many can spoil (many can spoil) But they can't repair Time no dey wait No dey explain Lókè lókè! sókè sókè! Gbé mi sókè! gbé mi sókè! Gbé mi dìde ee ah Lókè lókè! I keep on crying Gbé mi sókè Ekáalé ológì dé oo Èmi tí mo da tí o da (ahhn) Lókè lókè lolá kúnfàyà kún Àwon tó n bínú orí àsírí won ápadà tú Imam ríran sí mi l'asalatu Wóní má give up pé omo oró ápadà sùn Ojo ńsh'ojo odé ńsh'òdè Bàbá se ìlara omo ń sòtè Kòsí òfé àbí so fún mi Taló n se òfé? Wón ní Inú ìgbé lowó wà Maa foor towó bo ìgbé Ojú ení m'aalà árí tó K'omota tólè jeun seh akizo Tóbá di wáhàlá ámúgò But kòsí wàhálà fáwon omo ìyámi HarrySol Àlùbáríkà àní tálíkà Tímò n fa Tírà Lólá Satia Tawá ló sopé àní gba meter As my papa used to say Ómó mi má loma gbàgbé And like my papa used to say Ómó mi time no dey wait Lókè lókè! sókè sókè! Gbé mi sókè! gbé mi sókè! Gbé mi dìde ee ah Lókè lókè! I keep on crying Gbé mi sókè Àlùbáríkà àní tálíkà Tímò n fa Tírà Lólá Satia Tawá ló sopé àní gba meter
Sanatçı: HARRYSOL
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 2:48
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
HARRYSOL hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı