ibukun joyce joel eyo medley şarkı sözleri
E yo ninu Oluwa, E yo Eyin t’okan re se dede Eyin t’o ti yan Oluwa L’ibanuje ati aro lo. E yo, e yo, E yo nin’Oluwa e yo E yo, E yo E yo nin’Oluwa e yo. E yo, to r’oun l’Oluwa L’aye ati l’orun pelu Oro re bor’ohun gbogbo O l’agbara l’ati gbala. Gba t’a ba n ja ija rere Ti ota fere bori yin Ogun Olorun t’a ko ri Poju awon ota yin lo.
Igbagbo mi duro lori
Eje atododo Jesu
N'ko je gbekele ohun kan
Leyin oruko nla Jesu
Mo duro le Krist' apata
Ile miran, iyanrin ni
B'ire ije mi tile gun
Ore-ofe Re ko yi pada
Bo ti wu k'iji na le to
Idakoro mi ko ni ye
Mo duro le Krist' apata
Ile miran iyanrin ni
Majemu ati eje Re
L'emi o ro mo b'ikunmi de
Gbati ohun aye bo tan
O je ireti nla fun mi
Mo duro le Krist' apata
Ile miran iyanrin ni ONA ara l’ Olorun wa
Ngba sise Re l’ aiye;
A nri ‘pase Re lor’ okun,
O ngun igbi l’ esin. Ona Re enikan ko mo,
Awamaridi ni;
O pa ise ijinle mo,
O sin se bi Oba.
Elo so f'araye
Pe Jesu nbo...
Pe Jesu nbo
Pe Jesu nbo
Eyin omo Ogun
E'da mure giri Ma beru mo, enyin mimo,
Orun t’ o su be ni,
O kun fun anu: y’o r'ojo
Ibukun sori nyin. lbase p’Oluwa Ko ti wa ni tiwa Lo ye k’awa ma wi Nigbat’ese gbogun tiwa.
Egbe: Ope ni f'Oluwa Oba wa Olore A s'eba kabiyesi A f'ope fun Jehofa T'o gba wa Iowo ota, A dupe Oluwa Nwon ‘ba bo wa mole Pelu agbara won, Ope ni f ’Oluwa, Ti ko jeki t’esu bori.
Egbe: Ope ni f'Oluwa... Mase da Oluwa l’ ejo,
Sugbon gbeke re le;
‘Gbat o ro pe O binu,
Inu Re dun si .
Ise Re fere ye wan a,
Y’o ma tan siwaju;
Bi o tile koro loni,
O mbo wa dun lola.
Elo so f'araye
Pe Jesu nbo..
Pe Jesu nbo
Pe Jesu nbo
Eyin omo Ogun
E'da mure giri