ibukun joyce joel iwo loba şarkı sözleri
Iwo l'oba taye at'orun nbo
Iwo l'oba taye at'orun nbo
Mo sa di o meta l'okan
Olorun ogo ooo
Mimo ninu ogo ooo
O nsola ninu ogo o
O d'ade ninu ogo o
Oba giga
Mo sa di o meta l'okan
Olorun ogo ooo
Mimo ninu ogo ooo
O njoba ninu ogo o
O tobi ninu ogo
Tiwa ni nse
Mo sa di o meta l'okan
Olorun ogo ooo