ifeoluwa olamigoke modupe ore şarkı sözleri

Alaarun opolo ole dupe ore baba Alaarun opolo ole moun ti o n se omumi ranti adete mewa ti O wo San sugbon okan lowa dupe okan to dupe yi ori anu gba mi O ni salai mo re re layemi o Ore sisun ore jiji kose fowora aanu ni morigba o ose Oluwa Modupe ore baba se Modupe ore mele salai Mo re Emi oni sa Emi Oni sa lai Emi Oni sa lai More baba Amope wa Fun ore to se Ore ririje Ore ririmu Adupe ore re Baba Ose ose ose Oma je ka gbomosin Oma je ka gbaya sin Ti le tebi tara lati january titi de December Oya wa lenu opawa mo O ose ose ose Kabioosi oba to mu Majemu se o, eledumare Akiikitan, akaikatan ni o Oyi pada ri beelo si ni maayi pa da ni gbogbo ojo Oba to n mu ojo ro lakoko re obato mu ogbele n wa
Sanatçı: Ifeoluwa Olamigoke
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 3:50
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
Ifeoluwa Olamigoke hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı