imodola mr wisdom maami şarkı sözleri
Mama mi oo abiamo ku Ishe
Olohun ni oo Sesan e Komani rogun Ekun
Abiamo oo mama mi oo Abiamo ku Ishe
Olohun ni Sesan e komani rogun Ekun
Mama mi abiamo shishe gan Oju rito Ninu oyun mi orifowon edo dunwon won gbakamu Tori omo ni lati eje Kiki di bashi Eran dojo tolohun femi simi Lara titi wa dojo Ikule irin ajo yen koni shere fa mama mi oni sunkun omo mama mi oni sunkun omo Wahala re oni ja sason
Mama mi oo abiamo ku Ishe Olohun Nii oo Sean we komani rogun Ekun