imoleayo bright ileri se şarkı sözleri
Ileri se Ileri se oh oh adupe
Olorun da majemu pelu wa
O mu ileri se
Ileri se Ileri se oh oh adupe
Olorun da majemu pelu wa
O mu ileri se
Ileri se Ileri se oh oh adupe
Olorun da majemu pelu wa
O mu ileri se
Ileri se Ileri se oh oh adupe
Olorun da majemu pelu wa
O mu ileri se
Awa o korin ayo
Fore toluwa se fun wa
Akaikatan lore baba o
Ninu aye wa
O da wa lare O se wa logo o
A o se ni dupe
A o se ni korin
A tun jijo ope fun olorun
Awa o korin ayo
Fore toluwa se fun wa
Akaikatan lore baba o
Ninu aye wa
O da wa lare O se wa logo o
A o se ni dupe
A o se ni korin
A tun jijo ope fun olorun
To mu ileri ise
Ileri se Ileri se oh oh adupe
Olorun da majemu pelu wa
O mu ileri se
Ileri se Ileri se oh oh adupe
Olorun da majemu pelu wa
O mu ileri se
Ileri ayo Ileri ogo
Ileri igbega
Ti olorun da fun mi o
O ba boju wole mu ileri re se
Asiko ti to
Olorun da majemu pelu wa
O mu leri se
Ore gbo
Ma se so ireti nu
Majemu ti baba ba o da
O wa sibe
Akoko na de
Lati mu leri se fun e
Ore tuju ka
Baba yio mu ileri se
Ileri se Ileri se oh oh adupe
Olorun da majemu pelu wa
O mu ileri se
Ileri se Ileri se oh oh adupe
Olorun da majemu pelu wa
O mu ileri se
Wa muse
Ileri ayo to ba mi da
O di dandan
Ko muse ninu aye mi
Ni Isreali
O mu ileri se iyanu lo je
O mu won la
Okun pupa ja
O mu ileri se
Ni ile samaria
Lo mu ileri se
Iyefun kan
A ta ni shikeli kan
Onileri ayo
Orile ede wa di owo re
Bawa tun se
Kaiye de wa lorun
Ileri se Ileri se oh oh adupe
Olorun da majemu pelu wa
O mu ileri se
Ileri se Ileri se oh oh adupe
Olorun da majemu pelu wa
O mu ileri se
Ore to se fun wa o por o
A o le pa mora
Awa a dupe
A tun sope f'eleruniyin
Ore to se lori aye wa
A o le pa mora
Awa a dupe
A tun sope f'eleruniyin
Ore to se fun wa o por o
A o le pa mora
Awa a dupe
A tun sope f'eleruniyin
Ife re lori wa por o
A o le mu mora rara
Awa a dupe
A tun sope f'eleruniyin
Ore to se fun wa o por o
Opor opor ko mama l'akawe
Awa a dupe
A tun sope f'eleruniyin