inioluwanimi iwo l'apata şarkı sözleri

Iwo Lapata To ga ju gbogbo oke lo Iwo Lapata To duro gboingboin Iwo Lapata o Ti mo feyin ti o Jesu Iwo Lapata o Ti mo simi le Eyin eniyan gbogbo Eje ki agbe oluwa ga Ohun li Apata wa Olugbala wa Agbara wa Asa wa Aabo wa Igbala wa Ile-iso giga wa Oluwa mbe olubukun si li Apata wa Iwo Lapata To ga ju gbogbo oke lo Iwo Lapata To duro gboingboin Eni ba gbekele o Eni ba gbekele o Yio dabi oke sioni Eni ba gbekele o Awa duro sinsin Jesu Iwo Lapata Ti mo feyin ti o Jesu Iwo Lapata Ti mo simi le Nwon wo o Imole si mo won oju ko si ti won Nitori Iwo Lapata Ti mo gb'oju le o Nitori o Iwo Lapata Ti mo gb'oju le o Iwo Iwo Lapata To ga ju gbogbo oke lo Iwo Iwo Iwo Lapata To duro gboingboin Eni to ba gbekele o Eni ba gbekele o Yio dabi oke sioni Eni ba gbekele o A duro sinsin Iwo Lapata Ti mo feyin ti Ti mo feyin ti o Jesu Atosimile Iwo Lapata Ti mo simi le Eni to ba Saferi o yio si ri o Nitori Iwo Lapata Mo fi gbogbo okan mi wa o Nitori o Iwo Lapata Mo fi gbogbo okan mi wa o Iwo Iwo Lapata To ga ju gbogbo oke lo E ga E ga Iwo Lapata To duro gboingboin Eni to ba gbekele o Eni ba gbekele o Yio dabi oke sioni Eni ba gbekele o Awa duro A duro sinsin Jesu Iwo Lapata Ti mo feyin ti o Jesu Atogbojule Iwo Lapata Ti mo simi le E ko gbogbo Ani yan yin le Ohun lo nse itoju wa Nitori Iwo Lapata To le toju mi Nitori o Iwo Lapata To le toju mi Iwo Lapata E ga ju gbogbo oke lo To ga ju gbogbo oke lo Iwo Lapata To wa duro gboingboin To duro gboingboin Eni to ba gbekele Eni ba gbekele o Yio dabi oke sioni Yio dabi oke sioni Eni ba gbekele Eni ba gbekele o Awa duro sinsin A duro sinsin Iwo Lapata Ti mo feyin ti Ti mo feyin ti o Iwo Lapata Ti mo wa simi le Ti mo simi le Eni Ti o ba sa pe oruko oluwa Li a o gbala Nitori Iwo Lapata To le gbami la Iwo Lapata To le gbami la Eyin li Apata Ti A simi le Iwo Lapata Ti o le gbami la Nitori pe E le gba wa la Iwo Lapata To le gbami la Gbogbo eni to ba wa o Yio si ri o Iwo Lapata To le gbami la Gbogbo eni to ba gbokan le o Yio si ri o Iwo Lapata To le gbami la Gbogbo eni to ba pe oruko re Li a o gbala Iwo Lapata To le gbami la Gbogbo eni to ba sa to o Yio ye Iwo Lapata To le gbami la Jesu Iwo Lapata To le gbami la Iwo Li Apata wa Iwo li Apata wa Ti A le pe nigba gbogbo Iwo Lapata To le gbami la Iwo Lapata To le gbami la Iwo Lapata To le gbami la
Sanatçı: INIOLUWANIMI
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 6:30
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
INIOLUWANIMI hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı