irawoanobi ewaorin imole şarkı sözleri

(Dandex the beat creator) Anobi dè Imole dèee Anobi dè Imole dèe oo Okunkun Aiye mi odi imole kedere Onishe nla Anobi dè Imole dèee Anobi dè Imole dèe oo (irawoanobi) Okunkun Aiye mi odi imole kedere Ode Lodimole (Rosulullah) Imolee (Rosulullah) Eniti akoko da (Rosulullah) Omo Aminatu (Rosulullah) Omo Abdullahi (Rosulullah) Imole o (Rosulullah) Anobi dè Imole dèee Anobi dè Imole dèe oo Okunkun Aiye mi odi imole kedere Onishe nlã Anobi dè Imole dèee (baarul anwaari) Anobi dè Imole dèe oo ( Yah Rosulullah) Okunkun Aiye mi odi imole kedere Hudal Anbiyahii Walil aoliyahi Walil asfiyãhi Ma alatkiyahi Waliyyul walãhi wahusnulhikahi Wamudli shafãhi anilashkiyãhi Seyyidunã Muhammad n alayhi salãmu Seyyidunã Muhammad n alayhi salãmu Ode Lodimole (Rosulullah) Imolee (Rosulullah) Eniti akoko da (Rosulullah) Omo Aminatu (Rosulullah) Omo Abdullahi (Rosulullah) Imole o (Rosulullah) Wakhairu rojãhi Liyaumin liqahi Wamaolaridã Wa ahlilwahi Wasirru rakhãhi Bidunibtirahi Zuralawfiyãhi Wa nuru ssamahi Sanahu ssanãhi Liratil alahi Rosulul hayãhi wabahrul hatohii Seyyidunã Muhammad n alayhi salãmu Anobi dè Imole dèee Anobi dè Imole dèe oo Okunkun Aiye mi odi imole kedere Onishe nla Anobi dè Imole dèee Anobi dè Imole dèe oo (irawoanobi) Okunkun Aiye mi odi imole kedere Ode Lodimole (Rosulullah) Imolee (Rosulullah) Eniti akoko da (Rosulullah) Omo Aminatu (Rosulullah) Omo Abdullahi (Rosulullah) Imole o (Rosulullah) Alambishãril maoludi Sharil ula wasuhdadi Sharil nnabiyyi ahmadin Sharihu robiyil awwali Ojo ibi anobi lotunde Mumini muminãtu otunya Fekantele naa ojoojumo Aiye lo ye koshi maa jodun Fun anobi taa be nishe si Agbaye lapapo kaafatan Ofi Quranu jishe pe Tunbelohun koshike wa ni Anobi ti kii binu Tabawa wonu osu ti a Bii Kiloburu kaayo katunjo Kamuojo ibi e larinrin Alailarojinle aawipe Emi tio si Lanki fodun Talori anobi fiwena Shey eda bi daddy e lo je Anobi tio le tan lai Titi nio maa shemi ati Fi aiye awa tele yanyan Kaleba Muhammad wole ola Ode Lodimole (Rosulullah) Imolee (Rosulullah) Eniti akoko da (Rosulullah) Omo Aminatu (Rosulullah) Omo Abdullahi (Rosulullah) Imole o (Rosulullah) Isimi anobi ni kokoro Doodo allahu saati o daju Otipe Timoti tenu mo Kosiyemeji omaa gbore Shey ifokanbale yen otiri Idamu aiye e aadire Botele tanobi otigba Visa dalujannah ni kia Ota aiye e oni roju Foruko anobi maa jagun Ooni kabamo kan rara Botele tanobi teramo Rosulullah Imolee (Rosulullah) Eniti akoko da (Rosulullah) Omo Aminatu (Rosulullah) Omo Abdullahi (Rosulullah) Imole o (Rosulullah) Bosu anobi shey ko ni were Maoludi lotun losi niomalo Towotalafia re mãnasi Waari pe oofi gbopo ore si Eyin anobi aolesheytan Titilai laoshi maa kii lo Nabiyyul humiyyi Anobi nuurul hudah Imãmul murasaleena Khaatimul anbiyahi Imãmul muslimeenah Seyyidul qaomi toha Imãmul mutakeenah Ode Lodimole anobi (Rosulullah) Imolee (Rosulullah) Eniti akoko da (Rosulullah) Omo Aminatu (Rosulullah) Omo Abdullahi (Rosulullah) Imole o (Rosulullah) Solãtullãhi thuma salãmu was'an Alal mukhtãri nabiyyinã Muhammad Alal mukhtãri nabiyyinã Muhammad Alal mukhtãri nabiyyinã Muhammad
Sanatçı: Irawoanobi ewaorin
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 6:18
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
Irawoanobi ewaorin hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı