israel de zion ogo f'olorun şarkı sözleri
Mo f'iyin f'oruko Re
Ogo f'Olorun mi
Mo f'iyin f'oruko Re o
Ogo f'Olorun mi
To the One
To the One who was
To the One who is
To the One who is to come
To come to come to come
Mo wa f'iyin f'oruko Re
Ogo f'Olorun mi
Awon orun n soro oruko Re
Ofurufu n fise Re han
Ninu gbogbo aye
Ko seni to dabi Re
O o o Baba was orun
Awon orun n soro oruko Re
Ofurufu n fise Re han
Ninu gbogbo aye
Ko seni to dabi Re
O o o Baba wa orun
Mo wa f'iyin f'oruko Re o
Ogo f'Olorun mi
Ogo f'Olorun lorun o
Mo f'iyin f'oruko Re
Ogo f'Olorun mi
To the One, to the One, to the One
To the One who was
To the One who is
To the One who is to come
To come to come to come
Mo wa f'iyin f'oruko Re
Ogo f'Olorun mi
Owo agbara Re n gbani
Owo agbara Re n gbani la o
Oruko Re n wonisan
O n fun ni layo
Ijoba Re n be sibe
Owa titi lae
Aditu l'oruko Re
Jesu Oba gbogbo aye
Melo ni ki n royin
Melo ni ki n so
Iyen bee ti tobi to
Ko lafiwe o
E Kaye irawo oju orun
E fun gbogbo won l'oruko
Lakoko te baa won da
Won f'ogo yin han
Mo wa f'iyin f'oruko Re o
Ogo f'Olorun mi
Mo gbe O ga gbope
Ogo f'Olorun lorun o
Mo f'iyin f'oruko Re
Ogo f'Olorun mi
To the One, to the One, to the One
To the One who was
To the One who is
To the One who is to come
To come to come to come
Gbogbo iyin f'oruko Re
Ogo f'Olorun mi
Oba mimo mimo mo gbe O ga
Ogo f'Olorun mi
Oba giga giga to gaa ju lo
Ogo f'Olorun mi
Awogba aarun mama gbeje
(Mama gbeje ohun kohun)
Ogo f'Olorun mi
Alagbara to gaa julo
Ogo f'Olorun mi
Iyin f'oruko Re
Ogo f'Olorun mi.

