kafayat quadri wa s'ile eko şarkı sözleri
Uuuuhhh Aaaaaaah
Aaaaaaah Aaaaaaah
Uuuuhhh Aaaaaaah
Aaaaaaah Aaaaaaah
Uuuuhhh Aaaaaaah
Aaaaaaah Aaaaaaah
Uuuuhhh Aaaaaaah
Ma wa s'ile eko ni ojojumo
Igba ayo l'onje fa wa omode
Ma gbagbe ore mi wa ba mi de be
Ma gbagbe ore mi jo wo wa ba mi de be
Mo ni o wa wa wa wa wa s'ile eko
Mo ni o wa o wa o wa o
Mo ni o wa wa wa wa wa s'ile eko
Mo ni o wa o wa o wa o
Ni gba ta wa l'omode a nlo s'ile eko
Gbogbo oun t'oluko ko wa lan f'eti gbo
Ni to ri nan la se wa d'eniyan nla
D'akun d'akun ore mi wa s'ile eko
Mo ni o wa wa wa wa wa s'ile eko
Mo ni o wa o wa o wa o
Mo ni o wa wa wa wa wa s'ile eko
Mo ni o wa o wa o wa o
Ile eko ni ojo jumo
Awon omode e
Pelu agbalagba
Dakun ore mi wa ba mi d'ebe
Wa ba mi d'ebe
Mo ni o wa wa wa wa wa s'ile eko
Mo ni o wa o wa o wa o
Mo ni o wa wa wa wa wa s'ile eko
Mo ni o wa o wa o wa o
Mo ni o wa wa wa wa wa s'ile eko
Mo ni o wa o wa o wa o
Mo ni o wa wa wa wa wa s'ile eko
Mo ni o wa o wa o wa o
Wa s'ile eko

