k.w.a.m health is wealth şarkı sözleri

E ribi 9ice ati K1 ara ba nbi If you wanna live long If you wanna stay strong If you wanna live long and stay strong Ile la loro Ile la loro Dokita a fun e ni imoran heh If you wanna live long and stay strong Ile la loro IIe la loro Dokita a fun e ni imoran heh Ogun ibile afun ni ni iwosan Oloyun a bi were Lai sise abe Ewe nje ogun nje (Kabiyesi o) Ma se logun without doctor’s prescription Mo n tenu mo Mo n tenu mo Call on doctor’s attention If you need solution Mo n tenu mo Adigun heh Mo n tenu mo To much is given Much is asked of them Ile a loro Ile a loro If you wanna live long and stay strong Ile la loro Ile la loro Dokita a fun e ni imoran heh If you wanna live long and stay strong Ile la loro Ilе la loro Dokita a fun e ni imoran heh Iwosan ti de o Alaboyun е mu ra o Bo ba se pe eni ba e Akinkoju a su Alaboyun o ni ibi omiran to le lo Ko ja si hospisitu Tori pe ile la loro o O se dada fun alaboyun sugbon Ema se fi iwosan si ile E o gbodo da ogun lo o Lai se ase dokita o If you wanna live long and stay strong Ile la loro Ile la loro Dokita a fun e ni imoran heh If you wanna live long and stay strong Ile la loro Ile la loro Dokita a fun e ni imoran heh Imo toto lo le segun arun gbogbo Efan to gboro Lo wa aran to lero Ki eku ile gba ko so fun ti oko Cleanliness is essential But your life is potential And the sound of times on your initial Imo toto bori arun mo le La se ni ka se itoju fun alaboyun Sheri alaboyun kef o wo bowo o Eja ka se itoju wa ni ayika wa If you wanna live long and stay strong Ile la loro Ile la loro Dokita a fun e ni imoran heh If you wanna live long and stay strong Ile la loro Ile la loro Dokita a fun e ni imoran heh If you wanna live long and stay strong Ile la loro Ilе la loro Dokita a fun e ni imoran heh If you wanna live long and stay strong Ile la loro Ile la loro Dokita a fun e ni imoran heh
Sanatçı: K.W.A.M
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 3:36
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
K.W.A.M hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı