lady evangelist ipadeola victoria atemi ati ara ile mi şarkı sözleri
Atemi ati ara ile mi
Awa fun ami ati ise iyanu
Atemi atawon ayanfe
Awa fun ami ati ise iyanu
Atemi
Atemi ati ara ile mi
Awa fun ami ati ise iyanu
Atemi atawon ayanfe
Awa fun ami ati ise iyanu
Botiwu ki esu hale to
Botiwu ki ota gbogun to
Botiwu ki ruke rudo po
Awa fun ati ise iyanu
Botiwu ki esu hale to
Botiwu ki ota gbogun to
Botiwu ki ruke rudo po
Awa fun ati ise iyanu
Atemi ati ara ile mi
Awa fun ami ati ise iyanu
Atemi atawon ayanfe
Awa fun ami ati ise iyanu
Botiwu ki iji le ja to
Botiwu ki ota hale to
Botiwu ki esu dede go
Awa fun ami ati ise iyanu
Botiwu ki iji le ja to
Botiwu ki ota hale to
Botiwu ki esu dede go
Awa fun ami ati ise iyanu
Atemi ati ara ile mi
Awa fun ami ati ise iyanu
Be lo luwa wi
Atemi atawon ayanfe
Awa fun ami ati ise iyanu
Oluwa loso fun mi be
Awa fun ami ati ise iyanu
Sugbon nisin siyin
Oluwa olorun mi
Ti fun mi ni isinmi
Ni iha gbogbo
Beeni ko si si ota
Tabi ibi kan ti ose si mi rara
Kosi ibi kan ti ose
Sugbon nisin siyin
Oluwa olorun mi
Ti fun mi ni isinmi
Ni iha gbogbo ohh
Beeni ko si si ota
Tabi ibi kan ti ose si mi rara
Kosi ibi kan ti ose
Kosi o
Kosi ibi kan ti ose si mi rara
Kosi rara rara
Kosi ibi kan ti ose
Oluwa to fin isinmi yi awon
Omo isreli ka
Onbe lo'ju ise
Oluwa ni amonami
Ati igbala mi
Tani emi yo beru
Oluwa lagbarami
Aya tani yo fomi
Kosi ibi kan ti ose si mi rara
Kosi ibi kan tio se
Kosi ibi kan ti ose si mi rara
Kosi ibi kan ti ose
Kosi ibi kan ti ose si mi rara
Kosi ibi kan ti ose
Ko si rara
Oru ni ki awama
Osupa mi ki yio wokun
Oluwa ni imole mi
Imole aini ipekun
Ojo awe mi dopin
Kosi ibi kan ti ose si mi rara
Kosi ibi kan ti ose
Kosi ibi kan ti ose si mi rara
Kosi ibi kan ti ose
Kosi rara
Kosi ibi kan ti ose si mi rara
Kosi ibi kan ti ose
Ko mama si rara
Kosi ibi kan ti ose si mi rara
Kosi ibi kan ti ose
Atemi ati ara ile mi
Ohun gbogbo to fi yimika pata
Awa fun ami ati ise iyanu
Atemi atawon ayanfe
Ohun gbogbo ti oluwa fi yimika pata
Awa fun ami ati ise iyanu
Oluwa loso fun mi be
Awa fun ami ati ise iyanu
Atemi ati ara ile mi
Awa fun ami ati ise iyanu
Atemi atawon ayanfe
Awa fun ami ati ise iyanu
Oluwa loso fun mi be
Awa fun ami ati ise iyanu
Atemi ati ara ile mi
Awa fun ami ati ise iyanu
Atemi atawon ayanfe
Awa fun ami ati ise iyanu
Oluwa loso fun mi be
Awa fun ami ati ise iyanu