lady evangelist ipadeola victoria ijoba orun de tan şarkı sözleri
Esin laisi igbala
Esin laisi igbala
Esin laisi igbala
Asan ni ayanfe ronu oh
Esin laisi igbala
Esin laisi igbala
Esin laisi igbala
Asan ni ayanfe ronu oh
Ijoba orun detan
Odetan
Ijoba orun detan
Otide
Ara mi o emura
Komo se ba o
Lai mura sile
Ijoba orun detan
Ijoba orun detan
Otide
Ara mi o emura komo se ba o
Lai mura sile
Ijoba orun detan
Ijoba orun detan
Odetan
Bi ole loru ni
Ijoba orun detan
Bi ole loru ni
Ara mi o emura komo se ba o
Lai mura sile
Ijoba orun detan
Baba ronu re wo
Kotope
Mama ronu re wo
Kotope
Sister eyi pada o
Kotope
Brother eyi pada
Kotope
Ayanfe eyi pada o
Kotope
Eyi pada o
Kotope
Ijoba orun detan
Ijoba orun detan
Otide
Ara mi o emura
Komo se ba o
Lai mura sile
Ijoba orun detan
Ijoba orun detan
Ara mi o emura
Komo se ba o
Lai mura sile
Ijoba orun detan
Ara kunrin ati ara binrin
Esin lai si igbala asan ni o
Eniyan le'je oni gbagbo
Ki osi je elesin
Ati esin abalaye
Ati esin beebe lo
Ti aba wo apere ni gidomu
Oje olukoni ni Israeli
John 3 vs 10
Jesu dahun osi wifun pe
Se olukoni ni isreli ni wo se
Iwo kosi mon nkan wonyii
Eniyan le sunmo
Olorun ninu esin
Ki oye igbala koi maye
Beeni opolopo ri
Anpe won mo olorun lara
Sugbon ise ati iwa won
Ko fi won han bi eni
Ti omo olorun
Ijoba orun detan
Ijoba orun detan
Otide
Ara mi o emura komo se ba o
Lai mura sile
Ijoba orun detan
Ijoba orun detan
Otide
Ara mi o emura komo se ba o
Lai mura sile
Ijoba orun detan
Opolopo gbekele
Igbagbo ara re
Aso wipe mon san
Ida mewa mi dede
Monyo saka
Koda
Odun orisa ile wa ajon seni
Mo so fun o
Esin lasan lasan ni
Rome 3 vs 23 wipe
Gbogbo eniyan ni o sa tise
Tiwon siti kuna ogo olorun
John 3 vs 16 wipe nitori
Olorun feran araye
Tobe ge tio fi
Omo bibi re kan soso funi
Ki enikeni toba gba gbo
Maba segbe
Sugbon ki o le ni iyi aini pekun
John 14 vs 6 wipe
Emi ni ona otito ati iye
Kosi eni keni ti ole losi
Odo baba bi kose nipase omo
Ijoba orun detan
Otide
Ijoba orun detan
Ara mi o emura komo se ba o
Lai mura sile
Ijoba orun detan
Otide
Ijoba orun detan
Ara mi o emura komo se ba o
Lai mura sile
Ijoba orun detan
Iwo ayanfe ton gbo mi lowo lowo
Nje omo pe
Ninu aye yi
Orisi ona meji ni owa
Ona abuja ati ona tojinna
Ona abuja je ona toya kankan
Nigba ti ona tojinna je
Ona ti ko rorun rara
Kogba eru idi kudi
Tori ona jin
Orun yio woni
Ore gbo emi ati iwo
Wa ni ona irin ajo
Oko to ko gbogbo wa
Papo ni aye ti awa yi
Bi eniyan ban lo si
Irin ajo ti ko mona
Ole sonu
John 23 vs 11 wipe
Ese mi ti tele
Ipase irin re
Ona re ni mo ki e si
Nko si ya kuro
Ijoba orun detan
Otide
Ijoba orun detan
Ara mi o emura komo se ba o
Lai mura sile
Ijoba orun detan
Odetan
Ijoba orun detan
Otide
Ara mi o emura komo se ba o
Lai mura sile
Ijoba orun detan
Otide
Eniyan lesina
Toripe ko mona
Sugbon eni toba
Bere ona kole sonu
Jesu kristi ni ona na
Ohun pe o si ona na loni
Isaiah 53 vs 6 wipe
Gbogbo wa ti sina
Kiri bi agutan
Oni kuluku wa ti tele
Ona arare
Oluwa siti mu aisi se dede
Wa pade lara re
Ore kinni yi je opin
Irin ajo re ninu aye yii
Fi aye re fun jesu loni
Yio si dara fun o
Gbogbo iwo ton
Gbo oro mi lowo lowo
Eo ni parun loruko jesu
Bi o tin pinu lati bo
Ninu iparun ayeraye
Gba adura yii pelu mi
Irugbin iparun ti
Satani ti fun sinu aye mi
Oluwa fa tu ki ofi jona
Ijoba orun detan
Otide
Ijoba orun detan
Ara mi o emura komo se ba o
Lai mura sile
Ijoba orun detan
Ijoba orun detan
Ijoba orun detan
Ara mi o emura
Komo se ba o
Lai mura sile
Ijoba orun detan
Ijoba orun detan
Yio de bi ole luru ni
Ijoba orun detan
Ara mi o emura
Komo se ba o
Lai mura sile
Ijoba orun detan
Ijoba orun detan
Otide
Ijoba orun detan
Ara mi o emura
Komo se ba o
Lai mura sile
Ijoba orun detan