lady evangelist ipadeola victoria oruko titun şarkı sözleri
Oruko titun
Oruko titun
Oruko titun
Ayemi ati iwo nilo
Oruko titun
Oluwa so fun Abraham
Ninu ise genesisi
Ori iketa din logun
Ese ikarun wipe
Aki yio pe o ni abram mo
Bi ko se Abraham
Emi yio si fi e se
Baba ori le ede pupo
Osi tun te si waju
Oso fun Abraham pe
Ni ti aya re aki yio pe ni
Sarai mo bi ko se
Serah ni oruko re yio moje
Ohun ohun si se
Iya opo orile ede
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Ogbologbo to kun fun egan
Ati abuku ti ati mo mimo
Mio fe mo
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Ogbologbo to kun fun egan
Ati abuku ti ati mo mimo
Mio fe mo
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Osa nu fun Jacob
Oso di Israel
Oyi oruko re po
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Osa nu fun saul
Oso di Pual
Oyi oruko re po
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Osa nu fun abram
Oso di Abraham
Oyi oruko re po
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Osa nu fun sarei
Oso di serah
Oyi oruko re po
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Ogbologbo to kun fun egan
Ati abuku ti ati mo mimo
Mio fe mo
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Osa nu fun jabesi
Olori buruku di olorire
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Igbeyin jobu
Odara ju ti isaaju relo
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Olorun ton so eru doba
Watun itan mi ko
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Oranti Joseph nile ajoji
Baba wa se iranti mi
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Omo eru ni esteri
Iwo loso esteri dayaba
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Ogbologbo to kun fun egan
Ati abuku ti ati mo mimo
Mio fe mo
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun
Ogbologbo to kun fun egan
Ati abuku ti ati mo mimo
Mio fe mo
Oluwa jowo oh
Funmi l'oruko titun