obioha ogbonna keresimesi ti de şarkı sözleri

Adupẹ o Baba Adupẹ o Jesu Adupẹ o Baba Adupẹ o Jesu Keresimesi Keresimesi Ti de o Awa juba Fun ọ Jesu Keresimesi Keresimesi Ti de o Olugbala Kristi de o Atiri irawọ ogo Keresimesi Idunnu siti ku aye Ayọ kun ọrun o Abi Jesu Olugbala Imanueli o Awọn angeli n k'ọrin ayọ Keresimesi ti de o Adupẹ o Baba Adupẹ o Jesu Adupẹ o Baba Adupẹ o Jesu Keresimesi Keresimesi Ti de o Awa juba Fun ọ Jesu Keresimesi Keresimesi Ti de o Olugbala Kristi de o Ẹk'ọrin Aleluya Alade ogo ti de Ẹk'ọrin Aleluya Alade ogo ti de Ọba ti de Ọba awọn ọba Jesu Ọba ti de Ọba awọn ọba Jesu Kristi Ka juba fun Ọba Olugbala ti de Ka juba fun Ọba Ẹk'ọrin Aleluya Ka juba fun Ọba Olugbala ti de Ka juba fun Ọba Ẹk'ọrin Aleluya o Olugbala wa kaabọ Olugbala wa ti de Olugbala wa kaabọ o Ẹse o Ẹmi Mimọ Ẹ bá wa kí Ọba wa Kú àbọ̀ Ọba È é é Àgbàlagbà ìgbàanì Ọba kọnrin kese kese Kọnrin Ọba ọlọkan funfun Aláwọ̀ funfun Onímọ̀ funfun Aládé funfun Kú abọ A n wa a n wa a n wa a n wa Ẹmi mimọ nirawọ A ti rin a ti rin a ti rin rin rin Irawọ lo gbewa de A gbagbọ ninu Mesaya Adari gbo gbo ẹda Ni bẹtẹlẹhẹmu la ti bi Olugbala yi o Atiri irawọ rẹ o O si n dan yan yan ni Ibukun ni fun Mariya Iya Ọba igbala Ọpẹ ọpẹ ni fun Josefu To duro ti imọlẹ wa Nibugbe ẹran latiri Ọba ogo Keresimesi ti de Olugbala wa de Irapada awa ti de o Oṣe Jesu o Oṣe Jesu Kabiyesi sí oò Oluwa Awa juba Kaabọ o Ehh Kabiyọ o si oo Eledumare to dáwà si eledua awa Ọbani E é e Ọbani Ahaaa Ọbani o Ọba àwọn ọba káàbọ ooo
Sanatçı: Obioha Ogbonna
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 4:43
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
Obioha Ogbonna hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı