qdot moriamo şarkı sözleri

Omo Adefi Omo Adefa loke Iresi Moriamo Alege Moriamo Iya baba mi sun re Ni'le aye 1980' something DaBeat Handle Damilare emi l'akobi bami Ki Qudus toh di Qdot Iya ati baba mi ti jaa o ti pe Kin toh wa'ye loti ni won le fe'ra won Okun ebi t'oba jaa welder kan o le jo alagbe K'Olohun f'orun ke Moriamo iya baba mi Moriamo omo Alege Iya ma n gb'omo ge ge ni Mama o gbe mi sile k'eyan kan kan toju mi Moriamo sun re sun re Mi o gbagbe oko Alado l'ona Erugbabu Oko obi yi Grandma ti foh loju kan Boya n tori obi toh ma ta ni muri kan Iya yi tun pada s'oko ada t'ohun t'oko ni Ori mi a wu toh ba pe ni oko mi Ojo ri je pelu ojo riri mu Mama ma n r'oka pelu Efo Bokolu Omi odo la ma n mu L'abule Ado l'abule Ado oh abule Ado Abule wa o jina si Shagamu A n pada s'oko ni motor jam o ma shee Mama ba n pariwo Damilare omolomo ni e ba n gbe O ma shee o ma shee Ojo yen ni mo mo pe iya yi ko lo bi mi Moriamo Alege Moriamo Moriamo Alege Moria oh Moriamo Alege Iya baba mi orun re e Moriamo Alege Moriamo Moriamo Alege Moria oh Moriamo Alege Iya baba mi orun re e orun re e Hmm ojo re bi ana nigba t'iku wole de Iya yi ti r'iku loshey ni n b'ode na K'oju mi ma ba r'ibi Rafiu aburo mi n gba boolu nita Mo wo'le pada mama ti d'oju bo'le Kayeefi loje mo saare pe baba mi Adio o wa dakun wa wo mama re A shey olojo lode oh Ngba t'ariwo ta lowo mi n wa kilode Kin toh mo ese ti pe Shifau pelu Mutairu beree si nke omije oh Won ni won o le sin mama Moni kilode Won ni emi o jade tan ahh Kofe fimi sile loh ni Ojo 'kini lo ikeji loh Ojo 'keta Moria dagbere fun'aye Moriamo Alege Moriamo Moriamo Alege Moria oh Moriamo Alege Iya baba mi orun re e Moriamo Alege Moriamo Moriamo Alege Moriamo Moriamo Alege Iya baba mi orun re e orun re e Moriamo Moriamo oh Moria dagbere fun'aye Odi'gba odi'gbere Moriamo Mama Shifau mama Mutairu Moriamo omo Alege orun re e Moriamo Ma ro'yin f'omo mi Moriamo oh Moriamo Moriamo oh Moriamo Moriamo Moriamo Alege Yeah who's here
Sanatçı: Qdot
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 3:32
Toplam: 12 kayıtlı şarkı sözü
Qdot hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı