r.e.m.i aderemi omo oba şarkı sözleri

Ati kekere ni mo ti ba won mo pe Gbogbo oun t'ondan ko ni wura (Gbogbo oun t'ondan ko ni wura) Mowo iwaju mo wo eyin oh B'a o r'eni gbokanle shey bi a tera m'ose eni Kaye ma se sio soro mi Ariyo, aridunu omo ni moje Ni k'olorun semi oh Aderemi omo oba Many were called, few were chosen Yet only the fittest can survive Eyan nla eyan pataki mo fe ba won da laye Oun rere mo fe ba won shey laye K'ole m'ole f'ayo s'ayo Ki'n ma r'ogun ati m'ole o lola kurisiyu oh Mele ni kan se oh Mele ni kan se Bi mo se'n korin ema bami kalo Ire ire Ire ire Ire ire Ire ire Ire owo, ire ayo Ire ire Ire ire Ire ire Ire ire Ire ire Ire ire Ire owo, ire ayo Ire ire Ire ire Gbogbo bi ole se'n anrun t'onsun falala o Onise n sise, adura a gba tan Won a lo n wose o (Won a lo n wose) Bi mo se'n jeun soke K'emi ma se jeun wale Oke Agba mo'n gun yi o Oke Agba mo'n gun yi o M'o gbodo jabo o Ire ire Ire ire Ire ire Ire ire Ire owo, ire ayo Ire ire Ire ire (Ire ire) Ile aye yi o gbagidi (Ire ire) Dayanmo won lo j'owo lo o (Ire ire) Gbogbo idile Bankole ni mo ki Victor slatt, detty go wild ire ni ti e O ni ba won jabo laye Babatunde semiu, tunasky autos Egbon mori yin o Investor BJ bami ki drizzy eleniyan Olowo ori oko malaysia Shobowale junior, natty 4kt, ogo bariga Adinlewa ayomide, road manager ti o common Abiona pelumi o pr way go Harvard Ajilore reliance, badman bully Gbogbo won lo ma n coordinate mi oh Mi o ni riyin banuje o
Sanatçı: R.E.M.I
Türü: Belirtilmemiş
Ajans/Yapımcı: Belirtilmemiş
Şarkı Süresi: 3:07
Toplam: kayıtlı şarkı sözü
R.E.M.I hakkında bilgi girilmemiş.

Fotoğrafı